Béèrè fún(Order)

Àwùjọ Ìwé Ìléwọ́ Ìhìn-rere Àti Bíbélì ń fúnni ní àwọn ìwé Ìhìn-rere ọ̀fẹ́ fún kíkà tí ara ẹni àti pínpín láti ṣe irànlọ́wọ́ ní títàn Ìhìn-rere káàkiri. A ń fúnni ní àwọn ìwé àṣàrò kúkúrú lórí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àkòrí àti ní onírúurú èdè tó lé ní ọgọ́rin (80+)