Àwọn Ìtọrẹ(Donations)

Àwùjọ Ìwé Ìléwọ́ Ìhìn-rere Àti Bíbélì jẹ́ àjọ ti kò ní èrè, tí ó gbẹ́kẹ̀lé àwọn ẹ̀bùn láti ṣe ìnáwó títẹ̀jáde àti àwọn akitiyan pínpín. A gba àtìlẹyìn rẹ láti fún wa ni irànlọ́wọ́ láti tan Ìhìn-rere ìyípadà ìgbésí ayé ènìyàn kálẹ̀!