Title here
Summary here
Tani ìwọ ń sìn? Níbo ni ọlọ́run tìrẹ ǹgbé? Ǹjẹ́ o tilẹ̀ wà láàyè? Kíni ohun tí o se fún ọ lónìí? Ǹjẹ́ o baa sọ̀rọ̀ lónìí? Ǹjẹ́ o fi ìdáhùn fún igbe ọkàn rẹ bí? Kíni ìwọ gbàgbọ́? Jẹ́ kí nse àfihàn Ọlọ́run òtítọ́ kan ti o ti ṣẹ́gun Sátánì , ọ̀tá wa ti o ga jù lọ . Òun ni Ọlọ́run Ẹlẹ́dàá, ti o fi kìkì ọ̀rọ̀ ni kan da ohun gbogbo. Bíbélì mímọ́ yíò sọ fún ọ nípa Ọlọ́run ọ̀run yii ti o da ènìyàn láti inú erùpẹ̀ ilẹ̀.
14 Ògú 2024 in Jésù 3 minutes