Ọjọ́ Iwájú

Ọjọ ti mo ri ofifo apo-iwẹ gba lati ọdọ ẹgbọn Baba mi ni mo mọ riri iwẹ gbigba lati okeere. Adirẹsi ti mbẹ lẹhin apo–we na pe perepere, Iye owo to a fi nfi iwe ransẹ ni a si san fun, sugbọn ko si ohun kan ninu apo – iwe na. Gbogbo wa ni a ma nri iwe gba lati igba – de igba bẹni a ko nani iru ẹkọ ti ẸMI ti a le kọ ninu awọn iwe wọnyi.

John N. Reynolds Ọkàn nínú àwọn ẹjọ́́ ti o gbádùn jùlọ ni tíì isọji ti mo rántí ni ti Ọ̀gbẹ́ni George Lennox, olókìkí olè ti n máa jí ẹṣin gbé ni agbègbè ìlú Jefferson. Ọ̀gbẹ́ni yìí nlo ìgbà kejì rẹ̀ ni ile ẹ̀wọ̀n ni àkókò ti ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ṣẹlẹ̀. Ìjọba ìbílẹ̀ ti Sedgwick ni o ti kọ́kọ́ júù sí ẹ̀wọ̀n ìgbà kíní nítorí ẹ̀sùn kan náà pé o ji ẹṣin gbé.

Ọjọ́ Iwájú 16 minutes