Ilé

Ẹ Káàbọ̀ sí ojú òpó wẹ́ẹ̀bù Tí Àwùjọ Ìwé Ìléwọ́ Ìhìn-rere ati Bíbélì

Àwọn ìwé àṣàrò kúkúrú/Àwọn Ìwé ìléwọ́

“Tani yio gun ori oke Oluwa lo? Tabi tani yio duro ni ibi-mimo re? Eniti o li owo mimo, ati aiya funfun: eniti ko gbe okan re soke so asan, ti ko si bura etan.” (Orin Dafidi 24:3-4). Nje Iwo a lee duro niwaju Olorun ni idajo pelu Iwo mimo ati aya funfun bi? Melo ninu wa lo lee so pe mo ni owo mimo ati aya funfun? Iseda eniyan ko lee duro niwaju Olorun. Olorun nilo lati se iranlowo pelu ona fun iwenimo. Nitorinaa, O ran Jesu lati rawapada ati lati we a won owo ati okan wa mo.

Ìtàn 9 minutes

Kíni Ìbẹ̀rù? Ìbẹ̀rù Ọlọ́run Ìbẹ̀rù Ọjọ́ Ọ̀la Ìbẹ̀rù Ìjákulẹ̀/Ìkùnà Ìbẹ̀rù Ìjìyà Ìbẹ̀rù Ikú. DI ÒMÌNIRA LỌ́WỌ́ ÌBẸ̀RÙ Kíni Ìbẹ̀rù? WhatÌbẹ̀rù Ọlọ́run IÌbẹ̀rù Ọjọ́ Ọ̀la Ọ̀pọ̀ lo mbẹ̀rù ọjọ́ ọ̀la nítorí ti wọn kò ni ìdarí/ètò fun ìgbésí aye won. Ni àìmọ ibi tí àwọn ńrè, ẹ̀rù èyí náà pàápàá a máa mu ọkàn wọn sàárẹ̀. Ọlọ́run mọ ohun to wa níwájú, ti won ba le gba láàyè láti tọ wọn, won ki yíò wa nínú ìgbésí aye ta ńgba kiri, ṣùgbọ́n èyí ti o ńlọ tààrà si ilé. sÌbẹ̀rù Ìjákulẹ/Ìkùnà Ìbẹ̀rù Ìjìyà Ìbẹ̀rù Ikú Jesu

Àlàáfíà 10 minutes

Tani ìwọ ń sìn? Níbo ni ọlọ́run tìrẹ ǹgbé? Ǹjẹ́ o tilẹ̀ wà láàyè? Kíni ohun tí o se fún ọ lónìí? Ǹjẹ́ o baa sọ̀rọ̀ lónìí? Ǹjẹ́ o fi ìdáhùn fún igbe ọkàn rẹ bí? Kíni ìwọ gbàgbọ́? Jẹ́ kí nse àfihàn Ọlọ́run òtítọ́ kan ti o ti ṣẹ́gun Sátánì , ọ̀tá wa ti o ga jù lọ . Òun ni Ọlọ́run Ẹlẹ́dàá, ti o fi kìkì ọ̀rọ̀ ni kan da ohun gbogbo. Bíbélì mímọ́ yíò sọ fún ọ nípa Ọlọ́run ọ̀run yii ti o da ènìyàn láti inú erùpẹ̀ ilẹ̀.

Jésù 3 minutes